4th Street Bar Hive-Bar

Hive-Bar Powered by Hive beta-fdb5b5b

Community post

Ibo re ni agbara re

images (30).jpg

Ibo re ni agbara re

Agbara lati so o si igbekun

Agbara lati tu o sile.

Nigba ti a ba gba ibon lowo alagbara

Nje o lagbara bi?

Bee gege ni eni ti o lu ibo re ni gbanjo.

Ebi eru ti o lu omo pa ko

eni ti o fi egba omo le eru lowo ni ka bi leere.

Aki ti ese bo odo tan

ki a tun maa pariwo otutu.

A ki gbe alaimokan si ori aleefa tan

ki a tun kigbe iya.

Ejeka roonu wa wo.

Ko si egbe ti o ma wipe eni buruku ni oun fakale.

Gbogbo oloselu ni n dara lasiko ibo.

Ise oludibo ni lati wa nipa oludije.

Oponu baale ni yoo yan olori Ogun re nipa oro orita.

Alaimokan eniyan ni n dibo fun aheso oro.

Mo wipe ibo re ni agbara re

Lo daradara

(Translation)

Your vote is your power

Power to put you in bondage

Power to free you from bondage

When a warrior is stripped of his gun

Is he still powerful?

Same thing applies to someone that sells his vote

It's not the fault of the slave that beat the boss's child to death

The fault lies with the boss that gives a slave the permission to beat his child

You can't enter a river

And complain of cold

You can't enthrone a novice

And complain of poverty

Let's call on our senses

No political party will tell you its candidate is not capable

All politicians are good when it's election time

It's the responsibility of the voter to make enquiries about the contestants.

Only a stupid ruler will choose the head of his troops by hearsay

Only a stupid person votes for rumors

Your vote is your power

Use it wisely

images (28).jpg

2 upvotes $0.00

Replies (2)

Review before signing

Posting as . Signing with . Keychain permission: Posting. Hive Keychain will ask you to approve this action next.


  
Technical details

Operation fingerprint: